Hébérù 5:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí gbogbo ẹni tí kò yéé mu wàrà kò mọ ọ̀rọ̀ òdodo, torí pé ọmọdé ni.+ 14 Àmọ́ àwọn tó dàgbà ni oúnjẹ líle wà fún, àwọn tó ti kọ́ agbára ìfòyemọ̀* wọn nípa bí wọ́n ṣe ń lò ó láti fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tó tọ́ àti ohun tí kò tọ́.
13 Torí gbogbo ẹni tí kò yéé mu wàrà kò mọ ọ̀rọ̀ òdodo, torí pé ọmọdé ni.+ 14 Àmọ́ àwọn tó dàgbà ni oúnjẹ líle wà fún, àwọn tó ti kọ́ agbára ìfòyemọ̀* wọn nípa bí wọ́n ṣe ń lò ó láti fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tó tọ́ àti ohun tí kò tọ́.