2 Kíróníkà 15:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ní tiyín, ẹ jẹ́ alágbára, ẹ má sì jẹ́ kí ìrẹ̀wẹ̀sì bá yín,*+ nítorí pé èrè wà fún iṣẹ́ yín.” 1 Kọ́ríńtì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní báyìí, ọ̀kan náà ni ẹni tó ń gbìn àti ẹni tó ń bomi rin jẹ́,* àmọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan máa gba èrè iṣẹ́ tirẹ̀.+ Ìfihàn 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo gbọ́ tí ohùn kan dún láti ọ̀run pé, “Kọ̀wé pé: Aláyọ̀ ni àwọn òkú tó kú ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Olúwa+ láti ìsinsìnyí lọ. Àní, ohun tí ẹ̀mí sọ nìyẹn, kí wọ́n sinmi kúrò nínú wàhálà wọn, torí àwọn ohun tí wọ́n ṣe ń bá wọn lọ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.”*
8 Ní báyìí, ọ̀kan náà ni ẹni tó ń gbìn àti ẹni tó ń bomi rin jẹ́,* àmọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan máa gba èrè iṣẹ́ tirẹ̀.+
13 Mo gbọ́ tí ohùn kan dún láti ọ̀run pé, “Kọ̀wé pé: Aláyọ̀ ni àwọn òkú tó kú ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Olúwa+ láti ìsinsìnyí lọ. Àní, ohun tí ẹ̀mí sọ nìyẹn, kí wọ́n sinmi kúrò nínú wàhálà wọn, torí àwọn ohun tí wọ́n ṣe ń bá wọn lọ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.”*