ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 15:51, 52
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Ẹ wò ó! Àṣírí mímọ́ ni mò ń sọ fún yín: Kì í ṣe gbogbo wa ló máa sùn nínú ikú, àmọ́ a máa yí gbogbo wa pa dà,+ 52 ní ìṣẹ́jú kan, ní ìpajúpẹ́, nígbà kàkàkí ìkẹyìn. Nítorí kàkàkí máa dún,+ a máa gbé àwọn òkú dìde ní àìlèdíbàjẹ́, a sì máa yí wa pa dà.

  • 1 Tẹsalóníkà 4:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 nítorí Olúwa fúnra rẹ̀ yóò sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run pẹ̀lú ìpè àṣẹ, pẹ̀lú ohùn olú áńgẹ́lì+ àti pẹ̀lú kàkàkí Ọlọ́run, àwọn tó ti kú nínú Kristi ló sì máa kọ́kọ́ dìde.+ 17 Lẹ́yìn náà, àwa alààyè tí a kù nílẹ̀ ni a ó gbà lọ pẹ̀lú wọn nínú àwọsánmà+ láti pàdé Olúwa+ nínú afẹ́fẹ́; a ó sì tipa báyìí máa wà pẹ̀lú Olúwa nígbà gbogbo.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́