ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 18:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Júù kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Àpólò,+ ọmọ ìbílẹ̀ Alẹkisáńdíríà, ó dé sí Éfésù; ọkùnrin sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ tó mọ Ìwé Mímọ́ dunjú ni. 25 Ọkùnrin yìí ti gba ẹ̀kọ́* nípa ọ̀nà Jèhófà,* iná ẹ̀mí sì ń jó nínú rẹ̀, ó ń sọ̀rọ̀, ó sì ń kọ́ni ní àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ Jésù lọ́nà tó péye, àmọ́ ìrìbọmi Jòhánù nìkan ló mọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́