ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 10:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ẹni tó ń rìn nínú ìwà títọ́ yóò máa rìn nínú ààbò,+

      Àmọ́ àṣírí ẹni tó ń sọ ọ̀nà ara rẹ̀ di wíwọ́ yóò tú.+

  • 2 Kọ́ríńtì 10:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nítorí kì í ṣe ẹni tó ń dámọ̀ràn ara rẹ̀ ni a tẹ́wọ́ gbà,+ bí kò ṣe ẹni tí Jèhófà* dámọ̀ràn.+

  • 1 Tímótì 5:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àwọn kan wà tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn máa ń hàn sí ọ̀pọ̀ èèyàn, ó sì máa ń yọrí sí ìdájọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àmọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àwọn míì máa ń hàn síta nígbà tó bá yá.+ 25 Bákan náà, iṣẹ́ rere máa ń hàn síta,+ a ò sì lè fi àwọn tí kò hàn síta pa mọ́ lọ títí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́