ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 8:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Torí rẹ ni wọ́n ṣe ń pa wá láti àárọ̀ ṣúlẹ̀; wọ́n ti kà wá sí àgùntàn tó wà fún pípa.”+

  • 1 Kọ́ríńtì 15:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Tó bá jẹ́ pé bíi tàwọn yòókù,* mo ti bá àwọn ẹranko jà ní Éfésù,+ àǹfààní wo ló máa ṣe mí? Tí a ò bá ní gbé àwọn òkú dìde, “ẹ jẹ́ ká máa jẹ, ká sì máa mu, torí ọ̀la la máa kú.”+

  • 2 Kọ́ríńtì 6:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+

  • 2 Kọ́ríńtì 6:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 bí ẹni tí a kò mọ̀, síbẹ̀ a dá wa mọ̀, bí ẹni tó ń kú lọ,* síbẹ̀, wò ó! a wà láàyè,+ bí ẹni tí wọ́n fìyà jẹ,* síbẹ̀ a kò fà wá lé ikú lọ́wọ́,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́