1 Kọ́ríńtì 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 kí ẹ fi irú ẹni bẹ́ẹ̀ lé Sátánì lọ́wọ́+ kí agbára ẹ̀ṣẹ̀ náà lè pa run, kí ipò tẹ̀mí ìjọ lè wà láìyingin ní ọjọ́ Olúwa.+
5 kí ẹ fi irú ẹni bẹ́ẹ̀ lé Sátánì lọ́wọ́+ kí agbára ẹ̀ṣẹ̀ náà lè pa run, kí ipò tẹ̀mí ìjọ lè wà láìyingin ní ọjọ́ Olúwa.+