-
2 Kọ́ríńtì 9:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ní ti iṣẹ́ òjíṣẹ́ tó wà fún àwọn ẹni mímọ́,+ kò pọn dandan kí n kọ̀wé sí yín, 2 torí mo mọ bó ṣe ń yá yín lára, mo sì fi ń yangàn lójú àwọn ará Makedóníà, pé ó ti pé ọdún kan báyìí tí Ákáyà ti múra tán, ìtara yín sì ti mú kí èyí tó pọ̀ jù nínú wọn gbára dì.
-