Ìṣe 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tí Sílà+ àti Tímótì+ wá láti Makedóníà, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mú kí ọwọ́ Pọ́ọ̀lù dí gan-an, ó ń jẹ́rìí fún àwọn Júù láti fi ẹ̀rí hàn pé Jésù ni Kristi náà.+
5 Nígbà tí Sílà+ àti Tímótì+ wá láti Makedóníà, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mú kí ọwọ́ Pọ́ọ̀lù dí gan-an, ó ń jẹ́rìí fún àwọn Júù láti fi ẹ̀rí hàn pé Jésù ni Kristi náà.+