Hébérù 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ máa ṣègbọràn sí àwọn tó ń mú ipò iwájú láàárín yín,+ kí ẹ sì máa tẹrí ba,+ torí wọ́n ń ṣọ́ ẹ̀ṣọ́ lórí yín* bí àwọn tó máa jíhìn,+ kí wọ́n lè ṣe é tayọ̀tayọ̀, kì í ṣe pẹ̀lú ẹ̀dùn ọkàn, torí èyí máa pa yín lára.
17 Ẹ máa ṣègbọràn sí àwọn tó ń mú ipò iwájú láàárín yín,+ kí ẹ sì máa tẹrí ba,+ torí wọ́n ń ṣọ́ ẹ̀ṣọ́ lórí yín* bí àwọn tó máa jíhìn,+ kí wọ́n lè ṣe é tayọ̀tayọ̀, kì í ṣe pẹ̀lú ẹ̀dùn ọkàn, torí èyí máa pa yín lára.