-
Róòmù 16:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo rọ̀ yín pé kí ẹ máa ṣọ́ àwọn tó ń fa ìyapa àti ìkọ̀sẹ̀ tó lòdì sí ẹ̀kọ́ tí ẹ ti kọ́, kí ẹ sì yẹra fún wọn.+ 18 Nítorí irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ kì í ṣe ẹrú Olúwa wa Kristi, bí kò ṣe ti ohun tí wọ́n fẹ́ jẹ,* wọ́n máa ń fi ọ̀rọ̀ dídùn àti ọ̀rọ̀ ìpọ́nni fa ọkàn àwọn tí kò fura mọ́ra.
-