-
Fílípì 2:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Torí Ọlọ́run ni ẹni tó ń fún yín lágbára nítorí ìdùnnú rẹ̀, ó ń mú kó wù yín láti gbé ìgbésẹ̀, ó sì ń fún yín ní agbára láti ṣe é.
-