-
1 Kọ́ríńtì 15:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ẹ̀yin ará, ojoojúmọ́ ni mò ń dojú kọ ikú. Èyí dájú bí ayọ̀ tí mo ní lórí yín ṣe dájú, èyí tí mo ní nínú Kristi Jésù Olúwa wa.
-