ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 8:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ àwa fúnra wa pẹ̀lú tí a ní àkọ́so, ìyẹn, ẹ̀mí náà, bẹ́ẹ̀ ni, àwa fúnra wa ń kérora nínú ara wa,+ bí a ṣe ń dúró de ìsọdọmọ+ lójú méjèèjì, ìyẹn ìtúsílẹ̀ kúrò nínú ara wa nípasẹ̀ ìràpadà.

  • Éfésù 1:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Àmọ́ ẹ̀yin náà nírètí nínú rẹ̀ lẹ́yìn tí ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ òtítọ́, ìyẹn ìhìn rere nípa ìgbàlà yín. Lẹ́yìn tí ẹ gbà á gbọ́, a fi ẹ̀mí mímọ́ tí a ṣèlérí gbé èdìdì lé yín+ nípasẹ̀ rẹ̀, 14 ẹ̀mí mímọ́ yìí jẹ́ àmì ìdánilójú* ogún tí à ń retí,+ kí àwọn èèyàn* Ọlọ́run lè rí ìtúsílẹ̀+ nípasẹ̀ ìràpadà,+ sí ìyìn àti ògo rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́