ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 22:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “Júù+ ni mí, ìlú Tásù ní Sìlíṣíà+ ni wọ́n ti bí mi, àmọ́ ìlú yìí ni mo ti gba ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀* Gàmálíẹ́lì,+ wọ́n fi Òfin àwọn baba ńlá ìgbàanì dá mi lẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà àìgbagbẹ̀rẹ́,+ mo sì jẹ́ onítara fún Ọlọ́run bí gbogbo yín ṣe jẹ́ lónìí yìí.+

  • Fílípì 3:4-6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 torí náà, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tó ní ìdí láti gbẹ́kẹ̀ lé ẹran ara, èmi gan-an ní.

      Tí ẹlòmíì bá sì rò pé òun ní ìdí láti gbẹ́kẹ̀ lé ẹran ara, tèmi jù bẹ́ẹ̀: 5 mo dádọ̀dọ́* ní ọjọ́ kẹjọ,+ mo jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì, mo wá láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, Hébérù tó jẹ́ ọmọ bíbí àwọn Hébérù;+ ní ti òfin, mo jẹ́ Farisí;+ 6 ní ti ìtara, mo ṣe inúnibíni sí ìjọ;+ ní ti jíjẹ́ olódodo nínú pípa òfin mọ́, mo jẹ́ aláìlẹ́bi.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́