10 ẹ sì fi ìwà tuntun wọ ara yín láṣọ,+ èyí tí à ń fi ìmọ̀ tó péye sọ di tuntun, kí ó lè jọ àwòrán Ẹni tó dá a,+ 11 níbi tí kò ti sí Gíríìkì tàbí Júù, ìdádọ̀dọ́ tàbí àìdádọ̀dọ́, àjèjì, Sítíánì, ẹrú tàbí òmìnira; àmọ́ Kristi ni ohun gbogbo, ó sì wà nínú ohun gbogbo.+