Róòmù 8:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí ríronú nípa àwọn nǹkan tara ń yọrí sí ikú,+ àmọ́ ríronú nípa àwọn nǹkan tẹ̀mí ń yọrí sí ìyè àti àlàáfíà;+ Róòmù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 torí ó dájú pé ẹ máa kú, tí ẹ bá ń gbé ìgbé ayé tara; àmọ́ tí ẹ bá fi ẹ̀mí lu àwọn iṣẹ́ tara pa,+ ẹ ó yè.+
6 Nítorí ríronú nípa àwọn nǹkan tara ń yọrí sí ikú,+ àmọ́ ríronú nípa àwọn nǹkan tẹ̀mí ń yọrí sí ìyè àti àlàáfíà;+
13 torí ó dájú pé ẹ máa kú, tí ẹ bá ń gbé ìgbé ayé tara; àmọ́ tí ẹ bá fi ẹ̀mí lu àwọn iṣẹ́ tara pa,+ ẹ ó yè.+