Gálátíà 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 nígbà tí wọ́n rí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fún mi,+ Jémíìsì+ àti Kéfà* àti Jòhánù, àwọn tó dà bí òpó nínú ìjọ, bọ èmi àti Bánábà+ lọ́wọ́ láti fi hàn pé wọ́n fara mọ́ ọn pé* kí a lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè, kí àwọn sì lọ sọ́dọ̀ àwọn tó dádọ̀dọ́.
9 nígbà tí wọ́n rí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fún mi,+ Jémíìsì+ àti Kéfà* àti Jòhánù, àwọn tó dà bí òpó nínú ìjọ, bọ èmi àti Bánábà+ lọ́wọ́ láti fi hàn pé wọ́n fara mọ́ ọn pé* kí a lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè, kí àwọn sì lọ sọ́dọ̀ àwọn tó dádọ̀dọ́.