Éfésù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Èmi, tí mo kéré ju ẹni tó kéré jù lọ nínú gbogbo ẹni mímọ́,+ la fún ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí yìí,+ kí n lè kéde ìhìn rere nípa ọrọ̀ Kristi tí kò ṣeé díwọ̀n fún àwọn orílẹ̀-èdè,
8 Èmi, tí mo kéré ju ẹni tó kéré jù lọ nínú gbogbo ẹni mímọ́,+ la fún ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí yìí,+ kí n lè kéde ìhìn rere nípa ọrọ̀ Kristi tí kò ṣeé díwọ̀n fún àwọn orílẹ̀-èdè,