1 Tímótì 2:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí Ọlọ́run kan ló wà+ àti alárinà kan+ láàárín Ọlọ́run àtàwọn èèyàn,+ ọkùnrin kan, Kristi Jésù,+ 6 ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà tó bá a mu rẹ́gí fún gbogbo èèyàn*+—ohun tí a máa jẹ́rìí sí nìyí tí àkókò rẹ̀ bá tó.
5 Torí Ọlọ́run kan ló wà+ àti alárinà kan+ láàárín Ọlọ́run àtàwọn èèyàn,+ ọkùnrin kan, Kristi Jésù,+ 6 ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà tó bá a mu rẹ́gí fún gbogbo èèyàn*+—ohun tí a máa jẹ́rìí sí nìyí tí àkókò rẹ̀ bá tó.