9 Àmọ́ ní báyìí tí ẹ ti mọ Ọlọ́run, tàbí ká kúkú sọ pé, tí Ọlọ́run ti mọ̀ yín, kí ló dé tí ẹ tún ń pa dà sí àwọn ohun àkọ́bẹ̀rẹ̀ tó jẹ́ aláìlera+ àti aláìníláárí, tí ẹ sì tún fẹ́ ṣẹrú wọn?+ 10 Ẹ̀ ń pa àwọn ọjọ́ àti oṣù+ àti àsìkò àti ọdún mọ́ délẹ̀délẹ̀.