Róòmù 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ má sì jẹ́ kí ètò àwọn nǹkan yìí* máa darí yín, àmọ́ ẹ para dà nípa yíyí èrò inú yín pa dà,+ kí ẹ lè fúnra yín ṣàwárí+ ìfẹ́ Ọlọ́run tí ó dára, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà, tí ó sì pé. 1 Tẹsalóníkà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run jẹ́ nìyí, pé kí ẹ jẹ́ mímọ́,+ kí ẹ sì ta kété sí ìṣekúṣe.*+ 1 Pétérù 4:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 kó lè fi àkókò tó ṣẹ́ kù fún un láti gbé nínú ẹran ara ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run,+ kó má fi ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ èèyàn mọ́.+
2 Ẹ má sì jẹ́ kí ètò àwọn nǹkan yìí* máa darí yín, àmọ́ ẹ para dà nípa yíyí èrò inú yín pa dà,+ kí ẹ lè fúnra yín ṣàwárí+ ìfẹ́ Ọlọ́run tí ó dára, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà, tí ó sì pé.
2 kó lè fi àkókò tó ṣẹ́ kù fún un láti gbé nínú ẹran ara ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run,+ kó má fi ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ èèyàn mọ́.+