-
Éfésù 3:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ní àwọn ìran ìṣáájú, a kò fi àṣírí yìí han àwọn ọmọ èèyàn bí a ṣe fi han àwọn wòlíì àti àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ mímọ́ nípasẹ̀ ẹ̀mí lásìkò yìí,+ 6 ìyẹn ni pé, nínú Kristi Jésù àti nípasẹ̀ ìhìn rere, kí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè lè di ajùmọ̀jogún, kí a jọ jẹ́ ẹ̀yà ara kan náà,+ kí a sì jọ pín nínú ìlérí náà.
-