Kólósè 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé, láti ọjọ́ tí a ti gbọ́ nípa rẹ̀, a ò dákẹ́ àdúrà lórí yín,+ a sì ń bẹ̀bẹ̀ pé kí ẹ lè ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìmọ̀ tó péye+ nípa ìfẹ́ Ọlọ́run nínú gbogbo ọgbọ́n àti òye tẹ̀mí,+ 1 Tímótì 2:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+ 4 ẹni tó fẹ́ ká gba onírúurú èèyàn là,+ kí wọ́n sì ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́.
9 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé, láti ọjọ́ tí a ti gbọ́ nípa rẹ̀, a ò dákẹ́ àdúrà lórí yín,+ a sì ń bẹ̀bẹ̀ pé kí ẹ lè ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìmọ̀ tó péye+ nípa ìfẹ́ Ọlọ́run nínú gbogbo ọgbọ́n àti òye tẹ̀mí,+
3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+ 4 ẹni tó fẹ́ ká gba onírúurú èèyàn là,+ kí wọ́n sì ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́.