Àìsáyà 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Òdodo ló máa jẹ́ àmùrè ìgbáròkó rẹ̀,Òtítọ́ ló sì máa jẹ́ àmùrè ìbàdí rẹ̀.+