Kólósè 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lẹ́sẹ̀ kan náà, ẹ máa gbàdúrà fún wa+ pé kí Ọlọ́run ṣí ilẹ̀kùn fún ọ̀rọ̀ náà, kí a lè kéde àṣírí mímọ́ nípa Kristi, tí mo tìtorí rẹ̀ wà nínú ìdè ẹ̀wọ̀n,+
3 Lẹ́sẹ̀ kan náà, ẹ máa gbàdúrà fún wa+ pé kí Ọlọ́run ṣí ilẹ̀kùn fún ọ̀rọ̀ náà, kí a lè kéde àṣírí mímọ́ nípa Kristi, tí mo tìtorí rẹ̀ wà nínú ìdè ẹ̀wọ̀n,+