Mátíù 28:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jésù sún mọ́ wọn, ó sì sọ fún wọn pé: “Gbogbo àṣẹ ní ọ̀run àti ayé la ti fún mi.+ Éfésù 5:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 nítorí ọkọ ni orí aya rẹ̀+ bí Kristi ṣe jẹ́ orí ìjọ,+ òun sì ni olùgbàlà ara yìí. Kólósè 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 òun sì ni orí fún ara, ìyẹn ìjọ.+ Òun ni ìbẹ̀rẹ̀, àkọ́bí nínú àwọn òkú,+ kí ó lè di ẹni àkọ́kọ́ nínú ohun gbogbo;
18 òun sì ni orí fún ara, ìyẹn ìjọ.+ Òun ni ìbẹ̀rẹ̀, àkọ́bí nínú àwọn òkú,+ kí ó lè di ẹni àkọ́kọ́ nínú ohun gbogbo;