Sáàmù 145:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà ń ṣoore fún gbogbo ẹ̀dá,+Àánú rẹ̀ sì wà lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.