-
1 Kọ́ríńtì 12:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí bí ara ṣe jẹ́ ọ̀kan àmọ́ tó ní ẹ̀yà púpọ̀, tí gbogbo ẹ̀yà ara yẹn sì jẹ́ ara kan+ bí wọ́n tilẹ̀ pọ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni Kristi.
-