1 Kọ́ríńtì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó yẹ kí àwọn èèyàn kà wá sí ìránṣẹ́* Kristi àti ìríjú àwọn àṣírí mímọ́ Ọlọ́run.+ Éfésù 6:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ máa gbàdúrà fún èmi náà, kí a lè fún mi lọ́rọ̀ sọ tí mo bá la ẹnu mi, kí n lè fi ìgboyà sọ̀rọ̀ nígbà tí mo bá ń sọ àṣírí mímọ́ ìhìn rere,+
19 Ẹ máa gbàdúrà fún èmi náà, kí a lè fún mi lọ́rọ̀ sọ tí mo bá la ẹnu mi, kí n lè fi ìgboyà sọ̀rọ̀ nígbà tí mo bá ń sọ àṣírí mímọ́ ìhìn rere,+