Lúùkù 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ẹ bá ní ìfaradà, ẹ máa lè pa ẹ̀mí yín mọ́.*+ 2 Tẹsalóníkà 1:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí èyí, à ń fi yín yangàn+ láàárín ìjọ Ọlọ́run nítorí ìfaradà àti ìgbàgbọ́ yín nínú gbogbo inúnibíni àti àwọn ìṣòro* tí ẹ̀ ń dojú kọ.*+ 5 Èyí jẹ́ ẹ̀rí ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run, tó ń mú kí a kà yín yẹ fún Ìjọba Ọlọ́run tí ẹ̀ ń torí rẹ̀ jìyà.+
4 Nítorí èyí, à ń fi yín yangàn+ láàárín ìjọ Ọlọ́run nítorí ìfaradà àti ìgbàgbọ́ yín nínú gbogbo inúnibíni àti àwọn ìṣòro* tí ẹ̀ ń dojú kọ.*+ 5 Èyí jẹ́ ẹ̀rí ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run, tó ń mú kí a kà yín yẹ fún Ìjọba Ọlọ́run tí ẹ̀ ń torí rẹ̀ jìyà.+