22 Nígbà tí wọ́n débẹ̀, wọ́n fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn* lókun,+ wọ́n fún wọn ní ìṣírí láti má ṣe kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n sì sọ pé: “A gbọ́dọ̀ ti inú ọ̀pọ̀ ìpọ́njú wọ Ìjọba Ọlọ́run.”+
17 Nígbà náà, tí a bá jẹ́ ọmọ, ajogún ni wá pẹ̀lú, lóòótọ́ a jẹ́ ajogún Ọlọ́run, àmọ́ a jẹ́ ajùmọ̀jogún+ pẹ̀lú Kristi, kìkì tí a bá jọ jìyà,+ kí a lè ṣe wá lógo pẹ̀lú rẹ̀.+