2 Tímótì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 sí Tímótì, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́:+ Kí o ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí, àánú àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba àti látọ̀dọ̀ Kristi Jésù Olúwa wa.
2 sí Tímótì, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́:+ Kí o ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí, àánú àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba àti látọ̀dọ̀ Kristi Jésù Olúwa wa.