ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Gálátíà 2:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwa tí wọ́n bí ní Júù, tí a kì í ṣe ẹlẹ́ṣẹ̀ látinú àwọn orílẹ̀-èdè, 16 mọ̀ pé kì í ṣe àwọn iṣẹ́ òfin ló ń mú ká pe èèyàn ní olódodo, bí kò ṣe nípasẹ̀ ìgbàgbọ́+ nínú Jésù Kristi+ nìkan. Ìdí nìyẹn tí a fi ní ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù, kí a lè pè wá ní olódodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi, kì í ṣe nípasẹ̀ àwọn iṣẹ́ òfin, nítorí kò sí ẹni* tí a máa pè ní olódodo nípasẹ̀ àwọn iṣẹ́ òfin.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́