1 Kọ́ríńtì 14:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ̀yin ará, ẹ má ṣe di ọmọ kékeré nínú òye,+ àmọ́ ẹ di ọmọ kékeré ní ti ìwà burúkú;+ ẹ sì dàgbà di géńdé nínú òye.+ Hébérù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ àwọn tó dàgbà ni oúnjẹ líle wà fún, àwọn tó ti kọ́ agbára ìfòyemọ̀* wọn nípa bí wọ́n ṣe ń lò ó láti fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tó tọ́ àti ohun tí kò tọ́.
20 Ẹ̀yin ará, ẹ má ṣe di ọmọ kékeré nínú òye,+ àmọ́ ẹ di ọmọ kékeré ní ti ìwà burúkú;+ ẹ sì dàgbà di géńdé nínú òye.+
14 Àmọ́ àwọn tó dàgbà ni oúnjẹ líle wà fún, àwọn tó ti kọ́ agbára ìfòyemọ̀* wọn nípa bí wọ́n ṣe ń lò ó láti fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tó tọ́ àti ohun tí kò tọ́.