-
Éfésù 6:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Bákan náà, ẹ̀yin ọ̀gá, ẹ máa hùwà sí wọn lọ́nà kan náà, ẹ má ṣe máa halẹ̀ mọ́ wọn, torí ẹ mọ̀ pé Ọ̀gá wọn àti tiyín wà ní ọ̀run,+ kì í sì í ṣojúsàájú.
-