Ìṣe 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lẹ́yìn tó ti mọ ohun tó ṣẹlẹ̀, ó lọ sí ilé Màríà ìyá Jòhánù tí wọ́n ń pè ní Máàkù,+ níbi tí àwọn díẹ̀ kóra jọ sí, tí wọ́n ń gbàdúrà. Ìṣe 15:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Bánábà pinnu láti mú Jòhánù tí wọ́n ń pè ní Máàkù dání.+ Fílémónì 23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Épáfírásì+ tí a jọ wà lẹ́wọ̀n torí Kristi Jésù ń kí ọ, 24 Máàkù, Àrísítákọ́sì,+ Démà+ àti Lúùkù+ tí gbogbo wa jọ ń ṣiṣẹ́ tún kí ọ.
12 Lẹ́yìn tó ti mọ ohun tó ṣẹlẹ̀, ó lọ sí ilé Màríà ìyá Jòhánù tí wọ́n ń pè ní Máàkù,+ níbi tí àwọn díẹ̀ kóra jọ sí, tí wọ́n ń gbàdúrà.
23 Épáfírásì+ tí a jọ wà lẹ́wọ̀n torí Kristi Jésù ń kí ọ, 24 Máàkù, Àrísítákọ́sì,+ Démà+ àti Lúùkù+ tí gbogbo wa jọ ń ṣiṣẹ́ tún kí ọ.