Kólósè 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Inú rẹ̀ ni a fi gbogbo ìṣúra ọgbọ́n àti ti ìmọ̀ pa mọ́ sí.+ Kólósè 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 torí pé inú rẹ̀ ni gbogbo ànímọ́* Ọlọ́run pé sí.+