2 Kọ́ríńtì 5:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 ìyẹn ni pé Ọlọ́run mú ayé kan pa dà bá ara rẹ̀ rẹ́ nípasẹ̀ Kristi,+ kò ka àwọn àṣemáṣe wọn sí wọn lọ́rùn,+ ó sì fi ọ̀rọ̀ ìpadàrẹ́ sí ìkáwọ́ wa.+ Éfésù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 iṣẹ́ àbójútó kan* láti kó ohun gbogbo jọ nínú Kristi nígbà tí àwọn àkókò tí a yàn bá tó, àwọn ohun tó wà ní ọ̀run àti àwọn ohun tó wà ní ayé.+ Bẹ́ẹ̀ ni, nínú ẹni
19 ìyẹn ni pé Ọlọ́run mú ayé kan pa dà bá ara rẹ̀ rẹ́ nípasẹ̀ Kristi,+ kò ka àwọn àṣemáṣe wọn sí wọn lọ́rùn,+ ó sì fi ọ̀rọ̀ ìpadàrẹ́ sí ìkáwọ́ wa.+
10 iṣẹ́ àbójútó kan* láti kó ohun gbogbo jọ nínú Kristi nígbà tí àwọn àkókò tí a yàn bá tó, àwọn ohun tó wà ní ọ̀run àti àwọn ohun tó wà ní ayé.+ Bẹ́ẹ̀ ni, nínú ẹni