1 Kọ́ríńtì 15:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ dúró gbọn-in,+ ẹ má yẹsẹ̀,* kí ẹ máa ní ohun púpọ̀ láti ṣe+ nínú iṣẹ́ Olúwa nígbà gbogbo, kí ẹ sì mọ̀ pé làálàá yín kò ní já sí asán+ nínú Olúwa. Hébérù 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí àfi tí a bá ní irú ìdánilójú tí a ní níbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, la máa fi lè ní ìpín pẹ̀lú Kristi.*+
58 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ dúró gbọn-in,+ ẹ má yẹsẹ̀,* kí ẹ máa ní ohun púpọ̀ láti ṣe+ nínú iṣẹ́ Olúwa nígbà gbogbo, kí ẹ sì mọ̀ pé làálàá yín kò ní já sí asán+ nínú Olúwa.
14 Torí àfi tí a bá ní irú ìdánilójú tí a ní níbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, la máa fi lè ní ìpín pẹ̀lú Kristi.*+