Éfésù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Yàtọ̀ síyẹn, ó gbé wa dìde pa pọ̀, ó sì mú wa jókòó pa pọ̀ ní àwọn ibi ọ̀run ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù,+ Kólósè 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Tó bá jẹ́ pé a ti gbé yín dìde pẹ̀lú Kristi,+ ẹ máa wá àwọn nǹkan ti òkè, níbi tí Kristi jókòó sí ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run.+
6 Yàtọ̀ síyẹn, ó gbé wa dìde pa pọ̀, ó sì mú wa jókòó pa pọ̀ ní àwọn ibi ọ̀run ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù,+
3 Tó bá jẹ́ pé a ti gbé yín dìde pẹ̀lú Kristi,+ ẹ máa wá àwọn nǹkan ti òkè, níbi tí Kristi jókòó sí ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run.+