Sáàmù 110:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+ 1 Pétérù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ torí ó lọ sí ọ̀run; a sì fi àwọn áńgẹ́lì, àwọn aláṣẹ àti àwọn agbára sí ìkáwọ́ rẹ̀.+
110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+
22 Ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ torí ó lọ sí ọ̀run; a sì fi àwọn áńgẹ́lì, àwọn aláṣẹ àti àwọn agbára sí ìkáwọ́ rẹ̀.+