-
1 Kọ́ríńtì 15:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Torí ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ọba tí á máa ṣàkóso títí Ọlọ́run á fi fi gbogbo àwọn ọ̀tá sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀.+
-
-
Hébérù 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àmọ́ èwo nínú àwọn áńgẹ́lì ló sọ nípa rẹ̀ rí pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi, títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ”?+
-