Sáàmù 110:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+ 2 Jèhófà yóò na ọ̀pá agbára rẹ jáde láti Síónì, yóò sọ pé: “Máa ṣẹ́gun lọ láàárín àwọn ọ̀tá rẹ.”+
110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+ 2 Jèhófà yóò na ọ̀pá agbára rẹ jáde láti Síónì, yóò sọ pé: “Máa ṣẹ́gun lọ láàárín àwọn ọ̀tá rẹ.”+