ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 8:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Ta ló máa dá wọn lẹ́bi? Kristi Jésù ló kú, bẹ́ẹ̀ ni, yàtọ̀ síyẹn, òun la gbé dìde, tó wà ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tó sì ń bá wa bẹ̀bẹ̀.+

  • Éfésù 1:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 nígbà tó lò ó láti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú, tó sì mú un jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀+ ní àwọn ibi ọ̀run,

  • Hébérù 8:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Kókó ọ̀rọ̀ tí à ń sọ nìyí: A ní irú àlùfáà àgbà yìí,+ ó sì ti jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọba Ọlọ́lá ní ọ̀run,+

  • Hébérù 12:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 bí a ṣe ń tẹjú mọ́ Jésù, Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa.+ Torí ayọ̀ tó wà níwájú rẹ̀, ó fara da òpó igi oró,* kò ka ìtìjú sí, ó sì ti jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọlọ́run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́