Sáàmù 110:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+ Hébérù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó ń gbé ògo Ọlọ́run yọ,+ òun ni àwòrán irú ẹni tó jẹ́ gẹ́lẹ́,+ ó sì ń fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ tó lágbára gbé ohun gbogbo ró. Lẹ́yìn tó ti wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa mọ́,+ ó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún Ọba Ọlọ́lá ní ibi gíga.+
110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+
3 Ó ń gbé ògo Ọlọ́run yọ,+ òun ni àwòrán irú ẹni tó jẹ́ gẹ́lẹ́,+ ó sì ń fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ tó lágbára gbé ohun gbogbo ró. Lẹ́yìn tó ti wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa mọ́,+ ó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún Ọba Ọlọ́lá ní ibi gíga.+