Sáàmù 110:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+ Ìṣe 2:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ọlọ́run jí Jésù yìí dìde, gbogbo wa sì jẹ́rìí sí i.+ 33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde. Ìṣe 7:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Àmọ́ òun, tó ti kún fún ẹ̀mí mímọ́, ń wo ọ̀run, ó sì tajú kán rí ògo Ọlọ́run àti ti Jésù tó dúró ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+
110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+
32 Ọlọ́run jí Jésù yìí dìde, gbogbo wa sì jẹ́rìí sí i.+ 33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde.
55 Àmọ́ òun, tó ti kún fún ẹ̀mí mímọ́, ń wo ọ̀run, ó sì tajú kán rí ògo Ọlọ́run àti ti Jésù tó dúró ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+