Éfésù 1:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ó tún fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀,+ ó sì fi í ṣe orí lórí ohun gbogbo nínú ìjọ,+ 23 èyí tó jẹ́ ara rẹ̀,+ tó sì jẹ́ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹni tó ń fi ohun gbogbo kún inú ohun gbogbo.
22 Ó tún fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀,+ ó sì fi í ṣe orí lórí ohun gbogbo nínú ìjọ,+ 23 èyí tó jẹ́ ara rẹ̀,+ tó sì jẹ́ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹni tó ń fi ohun gbogbo kún inú ohun gbogbo.