Róòmù 12:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bí ẹ ṣe ń ṣe sí ara yín ni kí ẹ máa ṣe sí àwọn ẹlòmíì; ẹ má ṣe máa ronú nípa àwọn ohun ńláńlá,* àmọ́ ẹ máa ronú nípa àwọn ohun tó rẹlẹ̀.+ Ẹ má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara yín.+
16 Bí ẹ ṣe ń ṣe sí ara yín ni kí ẹ máa ṣe sí àwọn ẹlòmíì; ẹ má ṣe máa ronú nípa àwọn ohun ńláńlá,* àmọ́ ẹ máa ronú nípa àwọn ohun tó rẹlẹ̀.+ Ẹ má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara yín.+