Róòmù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí ìrunú Ọlọ́run+ ni à ń fi hàn láti ọ̀run sí gbogbo àìṣèfẹ́ Ọlọ́run àti àìṣòdodo àwọn èèyàn tí wọ́n ń tẹ òtítọ́ rì+ ní ọ̀nà àìṣòdodo,
18 Nítorí ìrunú Ọlọ́run+ ni à ń fi hàn láti ọ̀run sí gbogbo àìṣèfẹ́ Ọlọ́run àti àìṣòdodo àwọn èèyàn tí wọ́n ń tẹ òtítọ́ rì+ ní ọ̀nà àìṣòdodo,